Bawoni Oremi. Bawo Iowa?
Mowa dada. Ede yoruba mi da. Moni lati Ko gan. Se ole ranmi Iowo? Oruko mi ni Stephanie. Omo America nimi. Moferan yoruba. Se mole ko pelu e? Mase iwon ti mole se lati ko.
Dada ni mowa o! Ede Yoruba mi da sa, gbogbo ojo ti mo fin ko, ko kere o. Se ole ronmi lowo? Oruko mi n je Stephanie, America ni mo n gbe. Mo feran Ede Yoruba gan, Se mole ko pelu e?
note: i can't figure out what you are trying to say here "Mase iwon ti mole se lati ko", something along the line of giving you examples to work on?