Bawo ni!
Naijiria ni awon obi mi ti wa, sugbon, won bi mi ni London. Emi na, mo bi omode meta ti mo fe ko ede Yoruba.
Mo je alakowe, mo ti ko awon iwe meje. Mo fe mo lati ko'we dada ni Yoruba. Mo ti ko iwe omo kan ni Yoruba ati Twi (ede Ghana kan).
My parent are from Nigeria, but I was born in London. Me too, I have three children that I want to teach Yoruba.
I am a writer, I have written seven books. I want to know how to write well in Yoruba. I have written a children's book in Yoruba and Twi (a Ghanaian language).
다양한 영어 선생님을 검색해 보세요...
교정 · 2
1
Bawo ni!
Orile ede Naijiria ni awon obi mi ti wa, sugbon, won bi mi si Ilu London. Mo bi omo meta ti mo fe ko ni ede Yoruba. Mo je Onkowe, mo ti ko awon iwe meje. Mo fe mo lati ko'we dara dare ni ede Yoruba. Mo ti ko iwe awon omode kan ni Yoruba ati Twi (ede Ghana kan).
My parent are from Nigeria, but I was born in London. Me too, I have three children that I want to teach Yoruba. I am a writer, I have written seven books. I want to know how to write well in Yoruba. I have written a children's book in Yoruba and Twi (a Ghanaian language).
더 빨리 진행하고 싶나요?
이 학습 커뮤니티에 참여하고 무료로 연습해보세요!
집에서 편안하게 언어를 배울 수 있는 기회를 놓치지 마세요. 경험 많은 강사진을 살펴보고 지금 바로 첫 수업을 신청하세요!
오늘 학습 시작하기
