Adewale Titus
Community Tutor
A New Year's resolution is a tradition, most common in the Western World but also found in the Eastern World, in which a person resolves to continue good practices, change an undesired trait or behavior, accomplish a personal goal, or otherwise improve their behaviour. "Odin tuntun" Ninu odun tuntun mi orisirisi nkan ni mo se bi apere. 1. Mo rìn ìrin ajo lọ bá àwọn ẹbí mi lati lọ bá wọn se odun 2. Mo ko ede tuntun 3. Mo sì tún bá àwọn ọrẹ titun pade. Ati bẹbẹ lo
Feb 16, 2022 7:18 PM