Pesquise entre vários professores de Inglês...
United States flagEbun
5 Day Challenge Oruko film mo ti wo ni igba to koja ni, Bird Box. Mo ti wo flim yi lori Netflix. Mo gbdun flim. Eeyan to po ku ninu flim. Mo ti wo film yi pelu ore mi.

Correções · 1

0

5 Day Challenge

Yellow for the corrected text

This for the correction/addition

Orange for  expendable texts


Àkọ́léfilm fíìmù/sinimá mo ti wo  tí mo wò ni igba to koja  gbẹ̀yìn  ni Bird Box. Mo ti wo flim yi lori Netflix. Mo gbdun flim náà. Àwọn Eeyan to po ku ninu flim. Mo ti  ti here could mean "have", so it is not necessary :) wo film yi pelu ore mi.


Àkọ́lé fíìmù/sinimá tí mo wò gbẹ̀yìn ni Bird Box. Mo wo fíìmù yìí lóri Netflix. Mo gbádùn fíìmù náà. Àwọn èèyàn tó'kú nínú fíìmù yìí pọ̀ púpọ̀. Mo wo fíìmù yìí pẹ̀lú ọ̀rẹ́ mi. 

Keep it up Ebun! Super !!

Quer progredir mais rápido?

Junte-se a esta comunidade de aprendizagem e experimente exercícios grátis!

Não perca a oportunidade de aprender uma língua no conforto da sua casa. Navegue pela nossa seleção de professores de línguas experientes e inscreva-se na sua primeira aula agora mesmo!

Comece a aprender hoje