Ounje ti mo feran julo
Mo feran lati je ounje. Ounje ti mo feran julo ni adieye. Mo ni fe fun adieye to din. Ni osan yii mo je iresi ati fried stew pelu adieye.
Çeşitli İngilizce öğretmenleri arasından arama yapın...
Düzeltmeler · 1
1
Ounje ti mo feran julo
Mo feran lati máa ("máa" indicates continuity, it makes "je" to be continuous) je ounje. Ounje ti mo feran julo ni adieye. adìyẹ/ẹdìyẹMo ni fe fun sí (it is more common to use "fun" and love in regard to fellow humans than the inanimate) adieye to din díndín. Ni osan yii mo je iresi ati fried stew ọbẹ̀ ata díndín pelu adieye.Mo fẹ́ràn láti máa jẹ oúnjẹ. Oúnjẹ tí mo fẹ́ràn jùlọ ni adìyẹ/ẹdìyẹ. Mo ní ìfẹ́ sí adìyẹ/ẹdìyẹ díndín. Ní ọ̀sán yìí, mo jẹ ìrẹsì àti ọbẹ̀ ata díndín pẹ̀lú adìyẹ/ẹdìyẹ.
Still keep it up! Fluency abounds.
Daha hızlı mı ilerlemek istiyorsun?
Bu öğrenme topluluğuna katıl ve ücretsiz alıştırmaları dene!
Evden çıkmadan dil öğrenme fırsatını kaçırmayın. Deneyimli dil eğitmenlerimizden oluşan seçkimize göz atın ve ilk dersinize şimdi kaydolun!
Bugün öğrenmeye başlayın
