5 Day Challenge
Oruko film mo ti wo ni igba to koja ni, Bird Box. Mo ti wo flim yi lori Netflix. Mo gbdun flim. Eeyan to po ku ninu flim. Mo ti wo film yi pelu ore mi.
Busca entre varios profesores de Inglés...
Correcciones · 1
0
5 Day Challenge
Yellow for the corrected text
This for the correction/addition
Orange for expendable texts
Àkọ́lé fíìmù/sinimá tí mo wò gbẹ̀yìn ni Bird Box. Mo wo fíìmù yìí lóri Netflix. Mo gbádùn fíìmù náà. Àwọn èèyàn tó'kú nínú fíìmù yìí pọ̀ púpọ̀. Mo wo fíìmù yìí pẹ̀lú ọ̀rẹ́ mi.
Keep it up Ebun! Super !!
¿Quieres avanzar más rápido?
¡Únete a esta comunidad de aprendizaje y prueba ejercicios gratuitos!
No pierdas la oportunidad de aprender un idioma desde la comodidad de tu casa. ¡Explora nuestra selección de profesores de idiomas con experiencia e inscríbete ya en tu primera clase!
Empieza a aprender hoy
