多彩な 英語 講師陣から検索…
United States flagEbun
Kini mo ko ni eko ni ede Yoruba Mo ko ohun to po ni last eko ni ede Yoruba. Akroi ni gbogbo orin mo mo ni yoruba. Mo soro nipa elere gbajujbga ni Nigeria. Oluko mi bere lowo mi, gobogobo elere gbajujbga mo mo ni Nigeria. Mo ronu gan ni lati je pe mo le dahun oluko mi.

訂正 · 2

1

Kini mo ko ni eko ni ede Yoruba

Mo ko ohun to po ni last eko ni ede Yoruba. Akroi ni gbogbo orin mo mo ni yoruba. Mo soro nipa elere gbajujbga ni Nigeria. Oluko mi bere lowo mi, gobogobo elere gbajujbga mo mo ni Nigeria. Mo ronu gan ni lati je pe mo le dahun oluko mi.


Mo kọ́ ohun tó'pọ̀ nínú ẹ̀kọ́ èdè Yorùbá tí ó kọjá. Àkòrí wa dá ló'rí àwọn orin Yorùbá tí mo mọ̀ . Mo sọ̀rọ̀ nípa àwọn eléré gbajúgbajà ní Nàìjíríà. Olùkọ́ mi bèrè nípa gbogbo eléré gbajúgbajà tí mo mọ̀ ní Nàìjíríà lọ́wọ́ mi. Mo ronú gan ni kín n tó lè dá olùkọ́ mi lóhùn.   


Well done Ebun! Keep them coming. 

0
Kini mo ko ni eko ni ede Yoruba

Mo ko ohun to po ni eko ede Yoruba. Akole ni gbogbo orin mo mo ni yoruba. Mo soro nipa elere gbajumo ni Nigeria. Oluko mi bere lowo mi, gobogobo elere gbajumo ni mo mo ni Nigeria. Mo ronu gan ni lati le dahun oluko mi.

もっと早く上達したいですか?

この学習コミュニティに参加して、無料の練習問題を試してください!

ご自宅で快適に語学を学べるチャンスをお見逃しなく。経験豊富な語学講師陣の中からお選びいただき、今すぐ最初のレッスンにお申し込みください!

今すぐ学習を始める