多彩な 英語 講師陣から検索…
United States flagEbun
Ounje ti mo feran julo Mo feran lati je ounje. Ounje ti mo feran julo ni adieye. Mo ni fe fun adieye to din. Ni osan yii mo je iresi ati fried stew pelu adieye.

訂正 · 1

1

Ounje ti mo feran julo

Mo feran lati máa ("máa" indicates continuity, it makes "je" to be continuous) je ounje. Ounje ti mo feran julo ni adieye. adìyẹ/ẹdìyẹMo ni fe fun sí  (it is more common to use "fun" and love in regard to fellow humans than the inanimate) adieye to din díndín. Ni osan yii mo je iresi ati fried stew ọbẹ̀ ata díndín pelu adieye.


Mo fẹ́ràn láti máa jẹ oúnjẹ. Oúnjẹ tí mo fẹ́ràn jùlọ ni adìyẹ/ẹdìyẹ. Mo ní ìfẹ́ sí adìyẹ/ẹdìyẹ díndín. Ní ọ̀sán yìí, mo jẹ ìrẹsì àti ọbẹ̀ ata díndín pẹ̀lú adìyẹ/ẹdìyẹ.  


Still keep it up! Fluency abounds. 

もっと早く上達したいですか?

この学習コミュニティに参加して、無料の練習問題を試してください!

ご自宅で快適に語学を学べるチャンスをお見逃しなく。経験豊富な語学講師陣の中からお選びいただき、今すぐ最初のレッスンにお申し込みください!

今すぐ学習を始める