Laila
Ó da mi lẹru lati sọrọ niwaju awọn eniyan Lọla mo ni lati sọrọ niwaju awọn akẹkọọ ni yunifasiti. Ó da mi lẹru pupọ ṣugbọn mo gbiyanju lati ma fi eniyan han pe mo n gbọn. Mo nireti pe mo maa ṣe aṣeyóri ninu igbejade yii!
2014年12月18日 20:33
修正 · 5
2

Ó ba mi lẹru lati sọrọ niwaju awọn eniyan

Lọla mo ni lati sọrọ niwaju awọn akẹkọọ egbe mi ni Yunifasiti. Ó ba mi lẹru pupọ ṣugbọn mo n gbiyanju lati fi han awon eniyan wipe mo gbọ Yoruba.

Mo nireti pe mo maa ṣe aṣeyóri ninu igbejade yii!

2014年12月29日

Ó da mi lẹru lati sọrọ niwaju awọn eniyan

Lọla mo ni lati sọrọ niwaju awọn akẹkọọ ni yunifasiti. Ó ba mi lẹru pupọ ṣugbọn mo ni lati gbiyanju lati maa fi han pe mo n gbọn.

Mo nireti pe mo maa ṣe aṣeyóri ninu igbejade yii!
2016年9月27日
想進步快一點嗎?
加入此學習社群,來試做免費的練習吧!