Busca entre varios profesores de Inglés...
Publicaciones
5-Day Challange LLera L’oro (Health is Wealth) Mo ro pe ti gba eeyan ni llera, ti gba won ni asian, won ni l’oro no ni. Ni tori pe ti gba ara eeyan ko ya, won le ku, aye won maa pari. A gbodo toju ara wa.
8 de febrero de 2019
3
1
5-Day Challenge: Owo tabi Agbara Mo ro pe owo pataki ju Agbara. Ni tori pe, eeyan to ni agbara o gbodo ni owo papo. Ni aye yii owo je agbara. Ti gba eni keni ni owo won le ra eni kan kan won fe ra, won le ra agbara.
6 de febrero de 2019
0
0
5 Day Challenge: Orile-Ede Mi Mo gbe ni orile-ede United States of America. awon o bi mi bi mi ni Nigeria. Emi ni je Nigerian to gbe ninu diaspora. Mi o feran orile-ede United states of America, mi o le paro. Sugbon, mo dupe lowo olrun pe mo ni education to dara, ati ile to dara.
5 de febrero de 2019
1
0
Ounje ti mo feran julo Mo feran lati je ounje. Ounje ti mo feran julo ni adieye. Mo ni fe fun adieye to din. Ni osan yii mo je iresi ati fried stew pelu adieye.
4 de febrero de 2019
1
0
5 Day Challenge Oruko film mo ti wo ni igba to koja ni, Bird Box. Mo ti wo flim yi lori Netflix. Mo gbdun flim. Eeyan to po ku ninu flim. Mo ti wo film yi pelu ore mi.
3 de febrero de 2019
1
0
Kini mo ko ni eko ni ede Yoruba Mo ko ohun to po ni last eko ni ede Yoruba. Akroi ni gbogbo orin mo mo ni yoruba. Mo soro nipa elere gbajujbga ni Nigeria. Oluko mi bere lowo mi, gobogobo elere gbajujbga mo mo ni Nigeria. Mo ronu gan ni lati je pe mo le dahun oluko mi.
27 de enero de 2019
2
1
Ile eko Ni ojo Eti mo ma lo si ile eko. O pe gan ni ti mi o lo si ile eko. A ti gba isimi fun oshu kan. Mi o fe lo nibe ni ojo Eti sugbon o ku die ti mo ma pare gbogbo eko mo gbdo se. Mo ma pare eko ni oshu May, inu mi dun lati pare eko.
16 de enero de 2019
0
0
Describe the picture Eeyan to wa ni aworan naa je oyo aalafin . Oyo aalafin je Oba ni ipinle Oyo. Aaalafin joko s'ori aga. Aga ni awo wura ati pupa. Aaalafin de fela to da bi eti aja. Aalafin wo agbada blue. Agbada won wo tobi gan ni. Aalafin gbe ige (stick?) dani ninu owo won.
13 de diciembre de 2018
0
0
Bowo mo se ipese adiye lati jeun Akoko, mo gbodo lo si oja lati ra adiye aye. Nigbati mo de ile, mo ma dubu adiye, leyin naa mo ma fi omi kana lati bo. Mo ma fi omi gbona lori adiye ti mo ku lati je pe mo le tu iye kuro si adiye. leyin naa mo ma ge adiye ke ke ke ati mo ma fi omi ati osan wewe lori adiye lati mu un. Nigba yii mo ma fi gbogbo ohun ipese lori adiye. Mo ma bo adiye ati din adiye. Nigba yii mo ti si obe, o ku lati fi adiye mo ti pese ninu obe. Ounje ti jina.
12 de diciembre de 2018
0
0
Describe the picture in Yoruba Aworan yii fi a han iyara ni. iyara yii o ni aga meji. Aga je awo pupa. O da bi eeyan mu gbogbo iyara ki won to ya aworan. Ina merin o wan be ati aworan meji o wa lori wall. Eeyan o le wo Tv nitori pe tv wan be papa. Ibusun to wan be, mo le sun lori e, Ibusun o tobi gan ni.
29 de noviembre de 2018
1
1
Mostrar más