Notebook Entry 1
Mo fe lati ko Yoruba sile lojoumo. Loni mo fe salaye ara mi. Oruko mi ni Ebunoluwa, mo je omo orile-ede Nigeria. Won bi mi ni Nigeria sugbon nigbati mo n kere awon o bi mi gbe mi si America. Mo ti da gba ni America. Mo n gbe ni ipinle Rhode Island. Rhode island o ti kere ju gbgbo ipinle to wa ni America. Awon to bi mi ko da gba ni America da bi emi. Iya mi wa lati ipinle ougn. baba mi wa lati ipinle oyo. Mo feran awon to bi mi. Mo ni aburo kan. Oruko re ni oluwaseun. Omo odun 21 ni. O dabo
Cerca tra vari insegnanti di Inglese...
Correzioni · 2
0
Mo fe latini akosile ede Yoruba ni ojoojumon. Loni mo fe ko aroko nipa ara mi (composition about myself). Oruko mi ni Ebunoluwa, mo je omo orile-ede Nijeriya. Won bi mi ni Nijeriya sugbon nigbati mo wa ni omo ikoko (kid) awon o bi mi gbe mi wa si orile ede Amerika. Mo ti dagba si orile ede Amerika. Mo n gbe ni ipinle erekushu Roode(Rhode Island). Erekushu Roode ni okere ju ninu gbogbo ipinle ti o wa ni orile ede Amerika. Awon ti o bi mi ko da gba ni Amerika da bi emi. Iya mi wa lati ipinle Ogun, baba mi wa lati ipinle Oyo. Mo feran awon to bi mi. Mo ni aburo kan, oruko re ni Oluwaseun. Omo odun mokanlelogun ni (21 years old). O dabo
0
I am going to do a 30-day challenge writing in Yoruba.
Vuoi progredire più velocemente?
Unisciti a questa comunità di apprendimento e prova gli esercizi gratuiti!
Non perdere l'opportunità di imparare una lingua comodamente da casa tua. Esplora la nostra selezione di insegnanti di lingue esperti e iscriviti subito alla tua prima lezione!
Inizia a imparare oggi
