Cerca tra vari insegnanti di Inglese...
United States flagEbun
5 Day Challenge: Orile-Ede Mi Mo gbe ni orile-ede United States of America. awon o bi mi bi mi ni Nigeria. Emi ni je Nigerian to gbe ninu diaspora. Mi o feran orile-ede United states of America, mi o le paro. Sugbon, mo dupe lowo olrun pe mo ni education to dara, ati ile to dara.

Correzioni · 1

0

5 Day Challenge: Orile-Ede Mi

Mo n gbe ni orile-ede United States of America.Amẹ́ríkà  awon o bi  òbí mi bi mi ni Nigeria. Emi ni je Nigerian to gbe ninu diaspora. Mi o feran orile-ede United states of America, mi o le paro. Sugbon, mo dupe lowo olrun Ọlórun pe mo ni education ẹ̀kọ́ to dara, ati ile to dara.


Mo n gbé ní orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà. Àwọn òbí mi bí mi ní Nàìjíríà/a bí mi ní Nàìjíríà. Mo jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó n gbé ní òkè-òkun. Kí n má pa irọ́, mi ò fẹ́ràn orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà. Sùgbọ́n mo dúpé lọ́wọ́ Ọlórun pé mo ní ẹ̀kọ́ àti ilé tí ó dára. 


Insightful write-up Ebun. Please go through the correction, mostly the newly written paragraph and compare it with the former to have the grasp of some structures. Well done. 

Vuoi progredire più velocemente?

Unisciti a questa comunità di apprendimento e prova gli esercizi gratuiti!

Non perdere l'opportunità di imparare una lingua comodamente da casa tua. Esplora la nostra selezione di insegnanti di lingue esperti e iscriviti subito alla tua prima lezione!

Inizia a imparare oggi