5 Day Challenge: Orile-Ede Mi
Mo gbe ni orile-ede United States of America. awon o bi mi bi mi ni Nigeria. Emi ni je Nigerian to gbe ninu diaspora. Mi o feran orile-ede United states of America, mi o le paro. Sugbon, mo dupe lowo olrun pe mo ni education to dara, ati ile to dara.
ค้นหาจากครู ภาษาอังกฤษ หลากหลายคน...
การแก้ไข · 1
0
5 Day Challenge: Orile-Ede Mi
Mo n gbe ni orile-ede United States of America.Amẹ́ríkà awon o bi òbí mi bi mi ni Nigeria. Emi ni je Nigerian to gbe ninu diaspora. Mi o feran orile-ede United states of America, mi o le paro. Sugbon, mo dupe lowo olrun Ọlórun pe mo ni education ẹ̀kọ́ to dara, ati ile to dara.Mo n gbé ní orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà. Àwọn òbí mi bí mi ní Nàìjíríà/a bí mi ní Nàìjíríà. Mo jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó n gbé ní òkè-òkun. Kí n má pa irọ́, mi ò fẹ́ràn orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà. Sùgbọ́n mo dúpé lọ́wọ́ Ọlórun pé mo ní ẹ̀kọ́ àti ilé tí ó dára.
Insightful write-up Ebun. Please go through the correction, mostly the newly written paragraph and compare it with the former to have the grasp of some structures. Well done.
ต้องการความก้าวหน้าที่เร็วขึ้นหรือไม่
เข้าร่วมชุมชนแห่งการเรียนรู้และทดลองใช้แบบฝึกหัดฟรี!
Don’t miss out on the opportunity to learn a language from the comfort of your own home. Browse our selection of experienced language tutors and enroll in your first lesson now!
Start Learning Today
